Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 1:47 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn iranṣẹ ọba si wá lati sure fun oluwa wa, Dafidi ọba, pe, Ki Ọlọrun ki o mu orukọ Solomoni ki o sàn jù orukọ rẹ lọ, ki o si ṣe itẹ rẹ̀ ki o pọ̀ jù itẹ rẹ lọ. Ọba si gbadura lori akete.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 1

Wo 1. A. Ọba 1:47 ni o tọ