Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 1:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gẹgẹ bi mo ti fi Oluwa, Ọlọrun Israeli bura fun ọ, wipe, Nitõtọ Solomoni, ọmọ rẹ, yio jọba lẹhin mi, on o si joko lori itẹ mi ni ipò mi, bẹ̃ni emi o ṣe loni yi dandan.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 1

Wo 1. A. Ọba 1:30 ni o tọ