Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 1:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori o sọkalẹ lọ loni, o si pa malu ati ẹran ọlọra, ati agùtan li ọ̀pọ-lọpọ, o si pè gbogbo awọn ọmọ ọba, ati awọn balogun, ati Abiatari alufa; si wò o, nwọn njẹ, nwọn si nmu niwaju rẹ̀, nwọn si nwipe, Ki Adonijah ọba ki o pẹ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 1

Wo 1. A. Ọba 1:25 ni o tọ