Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hos 9:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn kì yio ta Oluwa li ọrẹ ọti-waini, bẹ̃ni nwọn kì yio mu u ni inu dùn: ẹbọ wọn yio ri fun wọn bi onjẹ awọn ti nṣọ̀fọ; gbogbo awọn ti o jẹ ninu rẹ̀ ni yio di alaimọ́: nitori onjẹ wọn kì yio wá si ile Oluwa fun ọkàn wọn.

Ka pipe ipin Hos 9

Wo Hos 9:4 ni o tọ