Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hos 7:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBATI emi iba mu Israeli li ara dá, nigbana ni ẹ̀ṣẹ Efraimu fi ara hàn, ati ìwa-buburu Samaria; nitori nwọn ṣeké; olè si wọle, ọwọ́ olè si nkoni lode.

Ka pipe ipin Hos 7

Wo Hos 7:1 ni o tọ