Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hos 5:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi mọ̀ Efraimu, Israeli kò si pamọ́ fun mi: nitori nisisiyi, Efraimu, iwọ ṣe agbère, Israeli si dibajẹ.

Ka pipe ipin Hos 5

Wo Hos 5:3 ni o tọ