Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hos 5:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Efraimu ri arùn rẹ̀, ti Juda si ri ọgbẹ́ rẹ̀, nigbana ni Efraimu tọ̀ ara Assiria lọ, o si ranṣẹ si ọba Jarebu; ṣugbọn on kò le mu ọ lara da, bẹ̃ni kò le wò ọgbẹ́ rẹ jiná.

Ka pipe ipin Hos 5

Wo Hos 5:13 ni o tọ