Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hos 4:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn rubọ lori awọn oke-nla, nwọn si sun turari lori awọn oke kékèké, labẹ igi oaku ati igi poplari ati igi ẹlmu, nitoriti ojìji wọn dara: nitorina awọn ọmọbinrin nyin yio ṣe agbère, ati awọn afẹ́sọnà nyin yio ṣe panṣagà.

Ka pipe ipin Hos 4

Wo Hos 4:13 ni o tọ