Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hos 2:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina li emi o ṣe padà, emi o si mu ọkà mi kuro li akokò rẹ̀, ati ọti-waini mi ni igbà rẹ̀, emi o si gbà irun agùtan ati ọgbọ̀ mi padà, ti mo ti fi fun u lati bò ihòho rẹ̀.

Ka pipe ipin Hos 2

Wo Hos 2:9 ni o tọ