Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hos 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si bẹ̀ ọjọ Baalimu wò li ara rẹ̀, ninu eyiti on fi turari joná fun wọn, ti on si fi oruka eti, ati ohun ọ̀ṣọ rẹ̀, ṣe ara rẹ̀ lọṣọ, ti on si tọ̀ awọn ayànfẹ́ lẹhìn lọ, ti on si gbagbe mi, ni Oluwa wi.

Ka pipe ipin Hos 2

Wo Hos 2:13 ni o tọ