Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hos 10:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ibi giga Afeni pẹlu, ẹ̀ṣẹ Israeli, li a o parun; ẹgún ọ̀gan on oṣuṣu yio hù jade lori pẹpẹ wọn; nwọn o si wi fun awọn oke-nla pe, Bò wa mọlẹ; ati fun awọn oke kékèké pe, Wó lù wa.

Ka pipe ipin Hos 10

Wo Hos 10:8 ni o tọ