Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hab 2:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Egbe ni fun ẹniti o wi fun igi pe, Ji; fun okuta ti o yadi pe, Dide, on o kọ́ ni! Kiyesi i, wurà ati fàdakà li a fi bò o yika, kò si si ẽmi kan ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Hab 2

Wo Hab 2:19 ni o tọ