Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hab 1:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẽṣe ti o mu mi ri aiṣedede, ti o si jẹ ki nma wò ìwa-ìka? nitori ikógun ati ìwa-ipá wà niwaju mi: awọn ti si nrú ijà ati ãwọ̀ soke mbẹ.

Ka pipe ipin Hab 1

Wo Hab 1:3 ni o tọ