Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gẹn 48:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Angeli na ti o dá mi ni ìde kuro ninu ibi gbogbo, ki o gbè awọn ọmọde wọnyi; ki a si pè orukọ mi mọ́ wọn lara, ati orukọ Abrahamu ati Isaaki awọn baba mi; ki nwọn ki o si di ọ̀pọlọpọ lãrin aiye.

Ka pipe ipin Gẹn 48

Wo Gẹn 48:16 ni o tọ