Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gẹn 42:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Josefu si ri awọn arakunrin rẹ̀, o si mọ̀ wọn, ṣugbọn o fi ara rẹ̀ ṣe àjeji fun wọn, o si sọ̀rọ akọ si wọn: o si wi fun wọn pe, Nibo li ẹnyin ti wá? nwọn si wipe, Lati ilẹ Kenaani lati rà onjẹ.

Ka pipe ipin Gẹn 42

Wo Gẹn 42:7 ni o tọ