Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gẹn 40:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe ni ijọ́ kẹta, ti iṣe ọjọ́ ibí Farao, ti o sè àse fun awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀ gbogbo: o si gbé ori olori agbọti soke ati ti olori awọn alasè lãrin awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Gẹn 40

Wo Gẹn 40:20 ni o tọ