Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gẹn 39:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Onitúbu si fi gbogbo awọn ara túbu ti o wà ninu túbu lé Josefu lọwọ; ohunkohun ti nwọn ba si ṣe nibẹ̀, on li oluṣe rẹ̀.

Ka pipe ipin Gẹn 39

Wo Gẹn 39:22 ni o tọ