Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gẹn 30:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ododo mi yio si jẹ mi li ẹrí li ẹhin-ọla nigbati iwọ o wá wò ọ̀ya mi: gbogbo eyiti kò ba ṣe abilà ati alami ninu awọn ewurẹ, ti kò si ṣe pupa rúsurusu ninu awọn agutan, on na ni ki a kà si mi li ọrùn bi olè.

Ka pipe ipin Gẹn 30

Wo Gẹn 30:33 ni o tọ