Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gẹn 30:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li akokò ìgba ikore alikama, Reubeni si lọ, o si ri eso mandraki ni igbẹ́, o si mú wọn fun Lea iya rẹ̀ wá ile. Nigbana ni Rakeli wi fun Lea pe, Emi bẹ̀ ọ, bùn mi ninu mandraki ọmọ rẹ.

Ka pipe ipin Gẹn 30

Wo Gẹn 30:14 ni o tọ