Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gẹn 2:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lati inu ilẹ li OLUWA Ọlọrun si ti dá ẹranko igbẹ gbogbo, ati ẹiyẹ oju-ọrun gbogbo; o si mu wọn tọ̀ Adamu wá lati wò orukọ ti yio sọ wọn; orukọkorukọ ti Adamu si sọ olukuluku ẹda alãye, on li orukọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Gẹn 2

Wo Gẹn 2:19 ni o tọ