Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gẹn 19:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i nisisiyi, emi li ọmọbinrin meji ti kò ti imọ̀ ọkunrin: emi bẹ̀ nyin, ẹ jẹ ki nmu wọn jade tọ̀ nyin wá, ki ẹnyin ki o si fi wọn ṣe bi o ti tọ́ loju nyin: ṣugbọn awọn ọkunrin wọnyi ṣa ni ki ẹ má ṣe ni nkan; nitorina ni nwọn sa ṣe wá si abẹ orule mi.

Ka pipe ipin Gẹn 19

Wo Gẹn 19:8 ni o tọ