Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Est 5:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi mo ba ri ore-ọfẹ loju ọba, bi o ba si wù ọba lati fi ohun ti emi ntọrọ fun mi, ati lati ṣe ohun ti emi mbère fun mi, jẹ ki ọba ati Hamani ki o wá si àse ti emi o si tun sè fun wọn, emi o si ṣe li ọla bi ọba ti wi.

Ka pipe ipin Est 5

Wo Est 5:8 ni o tọ