Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Est 2:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ wọnni, nigbati Mordekai njoko li ẹnu ọ̀na ile ọba, meji ninu awọn iwẹfa ọba, Bigtani ati Tereṣi, ninu awọn ti nṣọ iloro, nwọn binu, nwọn si nwá ọ̀na lati gbe ọwọ le Ahaswerusi ọba.

Ka pipe ipin Est 2

Wo Est 2:21 ni o tọ