Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 7:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati emi, ani Artasasta ọba paṣẹ fun gbogbo awọn olutọju iṣura, ti o wà li oke odò pe, ohunkohun ti Esra alufa, ti iṣe akọwe ofin Ọlọrun ọrun yio bère lọwọ nyin, ki a ṣe e li aijafara,

Ka pipe ipin Esr 7

Wo Esr 7:21 ni o tọ