Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 6:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati eyiti nwọn kò le ṣe alaini ẹgbọrọ akọmalu, ati àgbo, pẹlu ọdọ-agutan fun ẹbọ sisun si Ọlọrun ọrun, alikama, iyọ, ọti-waini pẹlu ororo, gẹgẹ bi ilana awọn alufa ti o wà ni Jerusalemu, ki a mu fun wọn li ojojumọ laiyẹ̀:

Ka pipe ipin Esr 6

Wo Esr 6:9 ni o tọ