Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 6:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki Ọlọrun ẹniti o mu ki orukọ rẹ̀ ma gbe ibẹ, ki o pa gbogbo ọba, ati orilẹ-ède run, ti yio da ọwọ wọn le lati ṣe ayipada, ati lati pa ile Ọlọrun yi run, ti o wà ni Jerusalemu. Emi Dariusi li o ti paṣẹ, ki a mu u ṣẹ li aijafara.

Ka pipe ipin Esr 6

Wo Esr 6:12 ni o tọ