Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 5:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nitorina, bi o ba wu ọba, jẹ ki a wá inu ile iṣura ọba ti o wà nibẹ ni Babiloni, bi o ba ri bẹ̃, pe Kirusi ọba fi aṣẹ lelẹ lati kọ ile Ọlọrun yi ni Jerusalemu, ki ọba ki o sọ eyi ti o fẹ fun wa nipa ọ̀ran yi.

Ka pipe ipin Esr 5

Wo Esr 5:17 ni o tọ