Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 5:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi ni nwọn si fi èsi fun wa wipe, Iranṣẹ Ọlọrun ọrun on aiye li awa iṣe, awa si nkọ́ ile ti a ti kọ́ li ọdun pupọ wọnyi sẹhin, ti ọba nla kan ni Israeli ti kọ́, ti o si ti pari.

Ka pipe ipin Esr 5

Wo Esr 5:11 ni o tọ