Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 2:47-58 Yorùbá Bibeli (YCE)

47. Awọn ọmọ Giddeli, awọn ọmọ Gahari, awọn ọmọ Reaiah,

48. Awọn ọmọ Resini, awọn ọmọ Nekoda, awọn ọmọ Gassamu,

49. Awọn ọmọ Ussa, awọn ọmọ Pasea, awọn ọmọ Besai,

50. Awọn ọmọ Asna, awọn ọmọ Mehunimi, awọn ọmọ Nefusimi,

51. Awọn ọmọ Bakbuki, awọn ọmọ Hakufa, awọn ọmọ Har-huri,

52. Awọn ọmọ Basluti, awọn ọmọ Mehida, awọn ọmọ Harṣa,

53. Awọn ọmọ Barkosi, awọn ọmọ Sisera, awọn ọmọ Tama,

54. Awọn ọmọ Nesia, awọn ọmọ Hatifa,

55. Awọn ọmọ awọn iranṣẹ Solomoni: awọn ọmọ Sotai, awọn ọmọ Sofereti, awọn ọmọ Peruda,

56. Awọn ọmọ Jaala, awọn ọmọ Darkoni, awọn ọmọ Giddeli,

57. Awọn ọmọ Ṣefatiah, awọn ọmọ Hattili, awọn ọmọ Pokereti ti Sebaimu, awọn ọmọ Ami.

58. Gbogbo awọn Netinimu, ati awọn ọmọ awọn iranṣẹ Solomoni, jẹ irinwo o din mẹjọ.

Ka pipe ipin Esr 2