Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 2:41-52 Yorùbá Bibeli (YCE)

41. Awọn akọrin: awọn ọmọ Asafu, mejidilãdoje.

42. Awọn ọmọ awọn adena: awọn ọmọ Ṣalumu, awọn ọmọ Ateri, awọn ọmọ Talmoni, awọn ọmọ Akkubu, awọn ọmọ Hatita, awọn ọmọ Ṣobai, gbogbo wọn jẹ, mọkandilogoje.

43. Awọn Netinimu: awọn ọmọ Siha, awọn ọmọ Hasufa, awọn ọmọ Tabbaoti.

44. Awọn ọmọ Kerosi, awọn ọmọ Siha, awọn ọmọ Padoni.

45. Awọn ọmọ Lebana, awọn ọmọ Hagaba, awọn ọmọ Akkubu,

46. Awọn ọmọ Hagabu, awọn ọmọ Ṣalmai, awọn ọmọ Hanani;

47. Awọn ọmọ Giddeli, awọn ọmọ Gahari, awọn ọmọ Reaiah,

48. Awọn ọmọ Resini, awọn ọmọ Nekoda, awọn ọmọ Gassamu,

49. Awọn ọmọ Ussa, awọn ọmọ Pasea, awọn ọmọ Besai,

50. Awọn ọmọ Asna, awọn ọmọ Mehunimi, awọn ọmọ Nefusimi,

51. Awọn ọmọ Bakbuki, awọn ọmọ Hakufa, awọn ọmọ Har-huri,

52. Awọn ọmọ Basluti, awọn ọmọ Mehida, awọn ọmọ Harṣa,

Ka pipe ipin Esr 2