Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 2:37-44 Yorùbá Bibeli (YCE)

37. Awọn ọmọ Immeri, ãdọtalelẹgbẹrun o le meji.

38. Awọn ọmọ Paṣuri, ojilelẹgbẹfa o le meje.

39. Awọn ọmọ Harimu, ẹgbẹrun o le mẹtadilogun.

40. Awọn ọmọ Lefi: awọn ọmọ Jeṣua ati Kadmieli ti awọn ọmọ Hodafiah, mẹrinlelãdọrin.

41. Awọn akọrin: awọn ọmọ Asafu, mejidilãdoje.

42. Awọn ọmọ awọn adena: awọn ọmọ Ṣalumu, awọn ọmọ Ateri, awọn ọmọ Talmoni, awọn ọmọ Akkubu, awọn ọmọ Hatita, awọn ọmọ Ṣobai, gbogbo wọn jẹ, mọkandilogoje.

43. Awọn Netinimu: awọn ọmọ Siha, awọn ọmọ Hasufa, awọn ọmọ Tabbaoti.

44. Awọn ọmọ Kerosi, awọn ọmọ Siha, awọn ọmọ Padoni.

Ka pipe ipin Esr 2