Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 2:34-45 Yorùbá Bibeli (YCE)

34. Awọn ọmọ Jeriko, ọtadinirinwo o le marun.

35. Awọn ọmọ Sanaa, egbejidilogun o le ọgbọn.

36. Awọn alufa; awọn ọmọ Jedaiah, ti idile Jeṣua, ogúndilẹgbẹrun o din meje.

37. Awọn ọmọ Immeri, ãdọtalelẹgbẹrun o le meji.

38. Awọn ọmọ Paṣuri, ojilelẹgbẹfa o le meje.

39. Awọn ọmọ Harimu, ẹgbẹrun o le mẹtadilogun.

40. Awọn ọmọ Lefi: awọn ọmọ Jeṣua ati Kadmieli ti awọn ọmọ Hodafiah, mẹrinlelãdọrin.

41. Awọn akọrin: awọn ọmọ Asafu, mejidilãdoje.

42. Awọn ọmọ awọn adena: awọn ọmọ Ṣalumu, awọn ọmọ Ateri, awọn ọmọ Talmoni, awọn ọmọ Akkubu, awọn ọmọ Hatita, awọn ọmọ Ṣobai, gbogbo wọn jẹ, mọkandilogoje.

43. Awọn Netinimu: awọn ọmọ Siha, awọn ọmọ Hasufa, awọn ọmọ Tabbaoti.

44. Awọn ọmọ Kerosi, awọn ọmọ Siha, awọn ọmọ Padoni.

45. Awọn ọmọ Lebana, awọn ọmọ Hagaba, awọn ọmọ Akkubu,

Ka pipe ipin Esr 2