Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 1:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni awọn olori awọn baba Juda ati Benjamini dide, ati awọn alufa, ati awọn ọmọ Lefi, pẹlu gbogbo awọn ẹniti Ọlọrun rú ẹmi wọn soke, lati goke lọ, lati kọ́ ile OLUWA ti o wà ni Jerusalemu.

Ka pipe ipin Esr 1

Wo Esr 1:5 ni o tọ