Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 8:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o wi fun mi pe, Ọmọ enia, gbe oju rẹ soke nisisiyi si ọ̀na ihà ariwa. Bẹ̃ni mo gbe oju mi soke si ọ̀na ihà ariwa, si kiye si i, ere owu yi niha ariwa li ati-wọle ọ̀na pẹpẹ.

Ka pipe ipin Esek 8

Wo Esek 8:5 ni o tọ