Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 8:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni mo wò, si kiye si i, aworán bi irí iná: lati irí ẹgbẹ rẹ̀ ani de isalẹ, iná; ati lati ẹgbẹ́ rẹ de oke, bi irí didan bi àwọ amberi.

Ka pipe ipin Esek 8

Wo Esek 8:2 ni o tọ