Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 8:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o mu mi wá si ilẹkun ẹnu-ọ̀na ile Oluwa, ti o wà nihà ariwa; si kiye si i, awọn obinrin joko nwọn nsọkun fun Tammusi.

Ka pipe ipin Esek 8

Wo Esek 8:14 ni o tọ