Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 7:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tulasì yio gori tulasi, irọkẹ̀kẹ yio si gori irọkẹ̀kẹ; nigbana ni nwọn o bere lọdọ woli; ṣugbọn ofin yio ṣegbé kuro lọdọ alufa, ati imọ̀ kuro lọdọ awọn agbà.

Ka pipe ipin Esek 7

Wo Esek 7:26 ni o tọ