Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 6:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si wipe, Ẹnyin oke-nla Israeli, ẹ gbọ́ ọ̀rọ Oluwa Ọlọrun; bayi li Oluwa Ọlọrun wi si awọn oke-nla, si awọn oke kekeke, si awọn odò siṣàn, ati si awọn afonifoji; kiyesi i, Emi, ani Emi, o mu idà wá sori nyin, emi o si pa ibi giga nyin run.

Ka pipe ipin Esek 6

Wo Esek 6:3 ni o tọ