Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 48:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ni àgbegbe Juda, lati ihà ila-õrun, de ihà iwọ-õrun ni yio jẹ ọrẹ ti ẹnyin o ta, ẹgbã-mejila, o le ẹgbẹrun ije ni ibú, ati ni gigùn, bi ọkan ninu awọn ipin iyokù, lati ihà ila-õrun, de ihà iwọ-õrun: ibi mimọ́ yio si wà lãrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 48

Wo Esek 48:8 ni o tọ