Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 48:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati lati ini awọn Lefi, ati lati ini ti ilu-nla na, lãrin eyiti iṣe ti olori, lãrin àgbegbe Juda, ati lãrin àgbegbe Benjamini, yio jẹ ti olori.

Ka pipe ipin Esek 48

Wo Esek 48:22 ni o tọ