Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 48:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati iyokù ni gigùn, ni ikọjusi ọrẹ ti ipin mimọ́ na, yio si jẹ ẹgbã-marun nihà ila-õrun, ati ẹgbã-marun nihà iwọ-õrun: yio si wà ni ikọjusi ọrẹ ipin mimọ́ na, ati ibisi rẹ̀ yio jẹ fun onjẹ fun awọn ti nsìn ni ilu-nla na.

Ka pipe ipin Esek 48

Wo Esek 48:18 ni o tọ