Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 48:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ni ikọjusi àgbegbe awọn alufa, ni awọn Lefi yio ni ẹgbã-mejila, o le ẹgbẹrun ni gigùn, ati ẹgbã-marun ni ibú: gigùn gbogbo rẹ̀ yio jẹ ẹgbã-mejila o le ẹgbẹrun, ati ibú rẹ̀, ẹgbã-marun.

Ka pipe ipin Esek 48

Wo Esek 48:13 ni o tọ