Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 46:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si pèse ọrẹ-ẹbọ jijẹ, efa fun ẹgbọ̀rọ akọ malu kan, ati efa kan fun agbò kan, ati fun awọn ọdọ-agutan gẹgẹ bi ọwọ́ rẹ̀ ba ti to, ati hini ororo kan fun efa kan.

Ka pipe ipin Esek 46

Wo Esek 46:7 ni o tọ