Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 46:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun mi pe, Eyi ni ibiti awọn alufa yio ma sè ọrẹ irekọja ati ọrẹ ẹ̀ṣẹ, nibiti nwọn o ma yan ọrẹ jijẹ; ki nwọn má ba gbe wọn jade si agbalá ode, lati sọ awọn enia di mimọ́.

Ka pipe ipin Esek 46

Wo Esek 46:20 ni o tọ