Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 46:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si pèse ọrẹ-ẹbọ jijẹ fun u lorowurọ̀, idamẹfa efa, ati idamẹfa hini ororo kan, lati fi pò iyẹfun daradara na; ọrẹ-ẹbọ jijẹ nigbagbogbo nipa aṣẹ lailai fun Oluwa.

Ka pipe ipin Esek 46

Wo Esek 46:14 ni o tọ