Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 44:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Niti pe ẹ mu ọmọ-ajèji, alaikọla aiya, ati alaikọla ara wa, lati wà ni ibi-mimọ́ mi, lati sọ ọ di alailọ̀wọ, ani ile mi, nigbati ẹ rú akara mi, ọ̀ra ati ẹjẹ, nwọn si bà majẹmu mi jẹ nipa gbogbo ohun-irira nyin.

Ka pipe ipin Esek 44

Wo Esek 44:7 ni o tọ