Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 44:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ti nwọn ṣe iranṣẹ fun wọn niwaju òriṣa wọn, nwọn si jẹ ohun ìdugbolu aiṣedede fun ile Israeli: nitorina ni mo gbe ọwọ́ mi soke si wọn, ni Oluwa Ọlọrun wi, nwọn o si rù aiṣedede wọn.

Ka pipe ipin Esek 44

Wo Esek 44:12 ni o tọ