Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 43:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si mu ninu ẹjẹ rẹ̀, iwọ o si fi si iwo mẹrẹrin rẹ̀, ati si igun mẹrẹrin ijoko na, ati si eti rẹ̀ yika: iwọ o si wẹ̀ ẹ̀ṣẹ rẹ̀ mọ́, iwọ o si ṣe etùtu rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 43

Wo Esek 43:20 ni o tọ