Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 43:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ijoko ni yio jẹ igbọ̀nwọ mẹrinla ni gigun ati mẹrinla ni ibú ninu igun mẹrẹrin rẹ̀; ati eti rẹ̀ yika yio jẹ́ abọ̀ igbọnwọ; ati isalẹ rẹ̀ yio jẹ igbọnwọ kan yika; atẹgùn rẹ̀ yio si kọjusi iha ila-õrun.

Ka pipe ipin Esek 43

Wo Esek 43:17 ni o tọ