Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 43:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi si ni iwọ̀n pẹpẹ nipa igbọnwọ; Igbọnwọ jẹ igbọnwọ kan ati ibú atẹlẹwọ kan; isalẹ rẹ̀ yio jẹ igbọnwọ kan, ati ibu rẹ̀ igbọnwọ kan, ati igbati rẹ̀ ni eti rẹ̀ yika yio jẹ ika kan: eyi ni yio si jẹ ibi giga pẹpẹ na.

Ka pipe ipin Esek 43

Wo Esek 43:13 ni o tọ